Itan Ilu Iwere-Oke - jerkand

Breaking

Comments system

BANNER 728X90

Sunday, 13 May 2018

Itan Ilu Iwere-Oke

Ilu Iwere-Oke wa ijoba ibile Iwa LCDA no ipinle Oyo. O je ilu ti o wa no ori oke ti ko le fi ara sin in. Ilu Iwere-Oke ni ilu ti o wa  lori oke tente ju a won iyokun ti o wa ni ijoba ibile Iwa LCDA ati ipinle Oyo lapapo. Ilu Okeho ni o gbee ni iha ila-oorun ti ilu Ilaji-Oke GBE ni Iwo oorun, ilu Ilero ni o wa ni apa Ariwa ti ilu Ayetoro-Oke wa ni gusi. Awon eniyan patakipataki ni o nti ti ilu jade, ti won je Ojogbon, Eni Iyin, Omoluwabi eniyan ti won wa ni ile, leyin odi ati kaakiri gbogbo agbaye.

No comments:

Post a Comment